Smiley face

Muyiwa Ademola tí padà sí kíláàsì gẹ́gẹ́ bí olùkọ́

Kosi bí ènìyàn tí wù kó lọ́gbọ́n tàbí ní imọ, tí ẹnì náà kò ba ni ifarabalẹ, yóò nira fún irú ẹni bẹẹ láti sọ alaimọkan di onímò kíkún.

Yàtò sì wí pé Muyiwa Ademola Authentic je ẹnikan tí iṣẹ́ tiata ye pupọ, ó jẹ́ orísìí ẹ̀dá kan to fara balẹ gan-an. Akosemọsẹ olukoni ni.

Authentic àti àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n tí wọn kò ara wọn jọ tí bẹ̀rẹ̀ si ni sọ àwọn ènìyàn di irawo nínú ìṣe fíìmù báyìí.

Fún àlàyé, pé number yìí 08156950358, 08183033830. Ire

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment