Smiley face

"Kosi ohun tó kàn mí pelu ayé Nìyí" - Toyin Abraham fàbínú yọ

Nígbà tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ń ro wí pé wàhálà láàárín Toyin Abraham àti Adeniyi Johnson tí rodo lọ mú mi, rúgúdù míì tú dabi wí pé ó fẹ́ súyọ pelu èsì tí Toyin fọ jáde láàárín ọsẹ to kọjá yìí.

Nínú iforowanilenuwo to wáyé pelu Alakada lọ ń tí ṣe àlàyé nipa ìṣe fíìmù rẹ àti erogba rẹ láti ṣe fíìmù tí yóò lamilaaka kárí ilé adúláwò àti agbaye.

Nínú itakurọsọ yìí ni wón ti béèrè lọ́wọ́ rẹ bóyá ó lè pé Adeniyi Johnson sì ìṣe tàbí kí wọn jọ sise pọ leyin iná ìfẹ́ wọn to ku.

Esi Toyin ni yìí:

"Ẹ jọọ, mi ò ni fẹ sọ ohunkóhun nípa Nìyí. Onikaluku tí bá tiẹ̀ lọ mọ dẹ tí tesiwaju pẹlu life mí. Mí ó ní anything ṣe pelu Nìyí mọ, mi ò dẹ ni fẹ ki ẹnikẹ́ni kò ọ̀rọ̀ sì mi lẹ́nu, " Toyin ṣàlàyé bẹẹ 

Lẹ́yìn ìpínyà láàárín Toyin Abraham ẹni tí a mọ sì Toyin Aimakhu tẹ́lẹ̀, Nìyí tí padà bẹ̀rẹ̀ ìfẹ́ tuntun pelu Seyi Edun tí òun náà jẹ osere. A tilẹ tún rí gbọ wí pé Nìyí àti Seyi tí ṣe ìgbéyàwó bonkelẹ. 

Toyin Abraham náà padà gbé omi ìfẹ́ tuntun kana pelu Ṣeun Egbegbe ṣùgbọ́n ìfẹ́ náà kò tọjọ kò tosu to fi tuka. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment