Smiley face

Ọjọ́ kẹwàá ni Timi Ẹdẹ ṣe ọdún kẹwàá lórí oyè. Gọngọ sọ!

Ilu Ede ò gbèrò lánàá, ọjọ́ kẹwàá oṣù kẹta ọdún 2018, nígbà tí Ọba Munirudeen Adesola Lawal, Timi tiluu Ede ṣe ayẹyẹ ọdun kẹwàá lórí oyè.

Àìmọye àwọn ọmọ ìlú Ede ni wọn padà wálé láti bá Eminisa 1 yọ. Lára àwọn àlejò pàtàkì ọjọ́ náà ni Ààrẹ ona Kakanfo Ilẹ̀ Yorùbá, Oloye Gani Adams.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment