Smiley face

Wọn ní Tunde tí yà were o: Ẹ wá gbọ ohun tó se

Arábìnrin kan tí ń jẹ Omobaorun Ajibade lọ gbé atejade yìí sórí ìkànnì Yoruba Dun lórí Facebook. 

"Olorun Koni Je A Kagbako o. Kini ki omo'birin yi se? O ni ore kunrin kan, tunde loruko e, awon mejeji jo nba ife won bo, nigba to ya ni tunde pe omo'birin yi lati lo mo awon obi e. 

Ni kukuru won se momi-nmo e ati idana, ni tunde ba so fun omobirin yi pe ko je kawon ni ibalopo(sex), ni omobirin yi ba yari pe odi ale ojo igbeyawo oun. Omobirin yi dele lati so fun iya e nitori OMIDAN NI(virgen), iya e ni se lehin idana ti ati mu ojo igbeyawo siwaju pe ko gba fun. 

Bi iya omobirin yi se soro lo ni oun ti gbo, nigba ti omobirin de odo tunde obe pe ko ma binu ojo pe oun ti gbo, oun ti gba inu tunde dun, won bere ere ife ni tunde ri pe OMIDAN NI (virgen) inu bi pe ta lo raye gbogbo wahala yi. 

Nigba ti omobirin yi nsunkun lo ni se ewo ni ki obirin para e mo ni? tunde be o ni oun ti gbo. tunde ra pepsi onike fun sugbon o ti fi nkan sii, nigba ti omu tan osun ni tunde ba pe ore timotimo pe ko wa ba oun ja ibale iyawo oun, ore tunde se nkan to fe fun, nigba ti obirin yi ri nkan to sele inu baje, tunde nbe. Se Ko Gbo Ebe?"


https://m.facebook.com/groups/250287078355942?view=permalink&id=1882709848446982


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment