Smiley face

Lẹta: "Ó ń semi bi kí n pa ara mi" - Obirin afẹsọna

Olayemi kíni mo lè ṣe? Ó ń ṣe mi bi kí n pa ara mi. Ọkùnrin tí èmi àti ẹ jọ ń fẹ́ ara wa bí ọdún kan sẹ́yìn, ní atí jọ ṣe ayẹyẹ introduction wa laipe yii eléyìí to larinrin gan-an.

Gbogbo àwọn ọrẹ mi lọ ń kí mi kú oriire nítorí won rí àwọn foto náà lórí Facebook mi.

Inú èmi náà dùn wí pé mi ó ni pé di ìyàwó ilé. Àwọn ènìyàn tilè ń bí mi wí pé ìgbà wo ni date wedding wa. Ṣùgbọ́n mo sọ fún wọn wí pé má jẹ kan mọ very soon.

Ṣùgbọ́n ní báyìí ọkọ mi ni oun ko ṣe mọ. Lẹ́yìn tí gbogbo ènìyàn ti mọ sì introduction wá. Gbogbo àwọn ènìyàn ní wón ti n bá mí bẹ ẹ, n se lo yari.

Awada ni mo pe tẹ́lẹ̀ Wọn ni tí mo bá ṣẹ ẹ ko so. Ṣùgbọ́n kò so ohunkóhun.

Ko gbé number mi mọ báyìí. Ìtìjú ti mú mi lọ delete gbogbo foto introduction wá lórí Facebook. Ṣùgbọ́n àwọn ẹniyan kii yẹ yomilenu wí pé ọkọ mi ńkọ́ àti wí pé ìgbà wo ni wedding wá. Ayé tí sú mi. Mí ó tilè mo ibi tí mo fẹ́ gba mọ.

Oruko mi ni ******

Arábìnrin tí mo fi orúkọ bo lasiri yìí ló ko leta sì mi. Mí ó tilè mo esi tí mo fẹ́ fún un, ọrọ náà pakasọ. Kini Ìmọ̀ràn yín fún un?

yemoford@gmail.com
@OlayemiOniroyin

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment