Smiley face

Àwọn ọmọ ìbejì ọkùnrin ọmọ ọdún mẹta ti won ba ara wọn sún tí dá wàhálà silẹ l'Eko

Òpin ayé tí de o! Ẹ WA GBỌ OHUN TÓ ṢẸLẸ̀.

Àwọn ọmọ ìbejì ọkùnrin, ọmọ ọdún mẹta, ni wọn ba ara wọn ní ajọsepọ ni àgbègbè Ajah to wá nílùú Eko.

Ìyá wọn, Patience Isua, yà fídíò àwọn ọmọ ìbejì náà níbi wọn ti ń bá ara wọn sún ó sì fi ranse sì bàbà wọn, Ogbeni Emmanuel, nítorí wọn kò jọwá papọ mọ gẹ́gẹ́ bí tọkọtaya.

Patience ṣe àlàyé wí pé, gbogbo ìgbà ni bàbá wọn má ń wá kò wọn láti lọ fara mọ́ ọ fún ìgbà díẹ̀.

Lẹ́yìn eléyìí, yóò tún dá wọn padà. Patience tú ṣàlàyé síwájú pé, gbogbo ìgbà tí àwọn ọmọ yìí bá ti ọ̀dọ̀ bàbà wọn dé, orisirisi ìwà ni wọn máa ń mú jáde eléyìí to má ń bá òun leru gẹ́gẹ́ bí abiyamọ.

Ó ni tí òun bá sọ fún bàbá wọn lórí fóònù, ìbínú ni yóò fà yọ ti yóò sì ṣe bẹ́ẹ̀ pa fóònù mọ òun létí. Patience ní ìdí pàtàkì ni yìí ti oun fi yà fídíò náà láti fìdí oro òun múlẹ̀ níwájú bàbà wọn.

Ìṣẹ̀lẹ̀ yìí tí dewaju ijoba ipinle Eko, àwọn ọlọ́pàá ti kó awon ọmọ ìbejì náà bá yìí. Bákàn náà ni ìwádìí tí bẹ̀rẹ̀.

Ṣùgbọ́n sá, ìbéèrè tí ń tawọ́- tasẹ̀ nínú mi ni wí pé, ibo ni àwọn ọmọ ọdún mẹta tí kọ ìbálòpò ọkùnrin sì ọkùnrin (homosexual)?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment