Smiley face

Aisha Abimbola (Ọmọge Campus) tí kọjá sọ́run nílùú Canada

Òṣerébìnrin ilẹ̀ Nàìjíríà, Aishat Abimbola tí gbogbo ènìyàn mo sì ọmọge Campus tí papoda lọ́jọ́ mẹẹdogun oṣù karùn-ún ọdún 2018. Òṣeré náà la gbo wí pé àìsàn jẹjẹrẹ ń baja eléyìí tí wọn tọju rẹ nílùú Canada. Ìlú Canada náà ni osere náà dákẹ sí

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment