Smiley face

"Odunlade ò rí pátá mi rí" - Eniola Ajao

Eniola Ajaola tí sọ ọ kedere wí pé kò sí ajosepo lọkọlaya láàárín òun àti Odunlade Adekola.

Nínú ifọrọwero pẹ̀lú òṣerébìnrin yìí ló ti se àlàyé wí pé, ajosepo àwọn ko ju oga sì ọmọọsẹ lọ.

"Bí mo ṣe sún mọ́ Odunlade bẹẹ naa ni Owokoniran náà sún mọ́ọ. To bá jẹ́ wí pé obìnrin ni òun náà, ó seése kí àwọn ayé sọ wí pé fifẹ ni àwọn náà ń fẹ́ ara wọn. Mi ò ti ṣe ìgbéyàwó ṣùgbọ́n mo ti ní afẹsọna tèmi," Eniola fi kún ọ̀rọ̀ rẹ bẹẹ.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment