Smiley face

Ìgbéyàwó òṣerébìnrin onitia míì tí tú ká? Ohun tí Ìrètí Osayemi sọ nípa ìdílẹ̀ rẹ ni yìí

Orisirisi ahesọ ọ̀rọ̀ lọ tí kún ìgboro báyìí wí pé òṣerébìnrin Ìrètí Osayemi náà tí pàdánù ìgbéyàwó rẹ pẹlu Bakare Adeoye.

Ṣùgbọ́n sá, àwọn oniroyin tí wá arẹwà obìnrin náà kan láti bèèrè nípa àwọn ìròyìn tí kò léṣẹ̀ nílé tí ń fò kiri nípa rẹ. "Mí kò mọ ibi tí àwọn ènìyàn tí gbó wí pé ìgbéyàwó mi ti tú ká, Ọlọ́run kò ni jẹ ka r'Esu. Kosi ohunkóhun to ṣe ìgbéyàwó mi ò. Àlàáfíà ni èmi àti ọkọ mi wá". - Ìrètí Osayemi

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment