Smiley face

Ọ̀rọ̀ tí Aisha Abimbola sọ kẹyin lórí whatsapp kó to kú ní yìí

Ali Baba, ogbontarigi alawada ilẹ̀ Nàìjíríà tí ṣe àfihàn itakurọsọ to wáyé kẹyin láàárín òun àti olóògbé Aisha Abimbola.

Nínú itakurọsọ orí ẹ̀rọ whatspps náà lo tí sọ fún Ali Baba wi pe, oun ti ń gbádùn diẹdiẹ ṣùgbọ́n ikú kò padà jẹ ki òṣerébìnrin tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ sí Ọmọge Campus naa padà wálé.

Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn tí a gbọ, àìsàn jẹjẹrẹ lo ṣekú pa onisẹ tíátà náà níbi tó ti ń gba ìtọ́jú ni orileede Canada.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment