Smiley face

Ká mú tẹ̀gàn kúrò, Telu rẹwà lọkunrin

Kò sí ohun tó burú láti nawọ́ ìfẹ́ si àwọn ẹ̀yà to kú lórílẹ̀ Nàìjíríà 🇳🇬 , sebi ọkàn náà ni gbogbo wa. Ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí ọba alayé, àti aṣáájú àṣà, mélòó nínú àṣà Yorùbá gan-an láti gbé lárugẹ?

Ká má parọ, Ọba Akanbi gbayì nínú aṣọ yinmirin 😂 Aṣọ náà rẹwà ó sì dabi ẹni wí pé wọn bí pẹ̀lú rẹ ni. Abdulrasheed Adewale Akanbi yẹ lẹni tí wọn gbé gẹ́gẹ́ bí ọmọ tuntun 👏 😂

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment