Smiley face

Wizkid bale ọba jẹ nílùú London!

Omilẹgbẹ èrò bí ọjọ́ àjíǹde ni wọn ya wo 02 Arena láti wá wòran Ayodeji ọmọ ológo dídán. Igba àkọ́kọ́ ni yìí nílùú London ti onkorin ilé adúláwò yóò ṣeré nínú gbogan náà lai si àlàfo kankan. Àwọn ènìyàn bí ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ́n ni wọn pariwo Wizzy Ọba Orin ilé adúláwò. Lai tigbá kan bọkan nínú, ọmọ Balogun mìgboro tìtì. #Yaga

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment