Smiley face

Aya Femi Gbajabiamila dira fún ayẹyẹ ọjọ́ ìbí àádọ́ta ọdún

Adari ọmọ ẹgbẹ́ to pọ̀ jù lọ nílé ìgbìmọ̀ aṣojú sofin Abuja, Femi Gbaja ṣe ajọyọ pẹ̀lú aya rẹ, Yemisi Gbaja, pẹ̀lú bo se pe ẹni àádọ́ta ọdún (50).

Kí n má parọ fún yín, Ọnarebu lo aya rẹ dáadáa.

Ìyá Karimọ to wá lẹ́yìn ilé wa, oyún kẹsàn-án lọ wà níkún rẹ báyìí kí Ọlọ́run bá mi sọ layọ. Ìyá Karimọ ò tí pé 40 ṣùgbọ́n ẹ ṣe bóyá ó ti lè ni 80 ni.

Tí òyìnbó bá lo ń kan kù, ó sì ṣe é lò fún àwa ènìyàn dúdú. Tí ènìyàn dúdú bá lo ń kan kù, walahi kondẹẹmu pátápátá ní. Bóyá ni bàbá Karimọ lè rí ọrùn wọ! Ó lo woman yẹn jatijati ni. 😂

Ẹniwee, Happy Birthday 🎂 Sisi Yemisi. Baba mo rí Gucci yín ó but mi ní so anything kí àwọn pípù yìí má lọ má pé mi ní Saliu Ẹlẹnu Gbọ̀ọ̀rọ̀.

Ó dà bọ̀!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment