Smiley face

Dangote kò àádọ́jọ (150) ọkọ̀ kalẹ fún àwon ọlọ́pàá

Dangote Foundation eléyìí to jẹ àjọ tí Alh Aliko Dangote gbé kalẹ láti lè fi má rán àwùjọ lọ́wọ́ tí pèsè àádọ́jọ (150) ọkọ fún ilé ìṣe ọlọ́pàá ilé Nàìjíríà láti gbógun ti ìdaràn. Àwọn ọkọ yìí ni wọn kò kọ́kọ́rọ́ rẹ̀ kalẹ fún oga ọlọ́pàá yán-ányán ni ilu ileese ọlọ́pàá to wá ní Ìlú Abuja.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment