Smiley face

"Bukola Sàràkí ni bàbá ìsàlẹ̀ wa" Awọn adigunjale banki Ọfa tí jẹwọ

Ni olu ileesẹ ọlọ́pàá nílùú Abuja, wọn ti ṣe àfihàn àwọn afurasi adigunjale tí wọn ṣekú pa àìmọye nílùú Offa, Ìpínlẹ̀ Kwara.

Àwọn afurasi adigunjale yìí sí ti jẹwọ wí pé àwọn ohun ìjà olóró àti ìbọn tí àwọn lo jẹ èyí tí gómìnà ipínlẹ̀ náà àti Ààrẹ ilẹ̀ ìgbìmọ̀ asofin àgbà Abuja, Bukola Sàràkí, kò fún àwọn ni àkókò ìdìbò.

Kódà, wọn rí orúkọ Sàràkí lára àwọn ọkọ̀ tí àwọn adigunjale náà ń lò . Ní báyìí, wọn ti fi ìwé pé Sàràkí láti wá wí tẹnu rẹ nípa ẹ̀sùn tí wọn fi kan an.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment