Smiley face

Ohun tí Muyiwa Ademola sọ nípa orekelẹwa aya rẹ ni yìí

"Olólùfẹ́ mi, aya mi, Akankẹ mi, bí mo bá wà sílè ilé ayé nígbà igba, ìwọ kan náà lọ má jẹ aya mi. Àìmọye ìdùnnú lọ fún mi ti mi ò lé ròyìn tán. Ó ní kí n dúró di Sande ká tó sariya, ṣùgbọ́n ara mi kò lélẹ̀ mọ. Jẹ ka bẹ̀rẹ̀ àríyá latoni ni lọ. Happy Birthday 🎂 ìyàwó mi". - Muyiwa Ademola tí bẹ̀rẹ̀ si ni yọ ọjọ́ ìbí aya rẹ silẹ

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment