Smiley face

"Ojú tí Nìyí, Toyin Abraham ti pàdé ọkọ tuntun oloriire" - Àwọn tí Toyin fò fáyọ̀

"Ojú ti Nìyí aronipin! " Awọn olólùfẹ́ Toyin Abraham ti gbogbo ènìyàn mọ sì Toyin Aimakhu tẹ́lẹ̀ tí ń bá yọ báyìí pẹ̀lú bi òṣerébìnrin náà ṣe ṣe àfihàn òrùka ìgbéyàwó tuntun tó wà lọ́wọ́ rẹ.

Àwọn olólùfẹ́ Alakada kò sai ju òkò ọ̀rọ̀ padà sí Adeniyi Johnson to jẹ ọkọ rẹ àtijọ́ wí pé, ojú tí tì báyìí pẹ̀lú gbogbo akọ rẹ ń tí ń ṣe kiri nígbà tó rò wí pé Toyin kò lè rọkọ fẹ́ mọ.

Arábìnrin kan tí ń jẹ Sade Bakare tí lè ń sepe lórí ayélujára ni. O ni, "Nìyí máa padà sunkún ni at last pẹ̀lú wereh alasọ tí wọn jọ ń gbé ara wọn kiri".

Bákan náà madam Kofo, eléyìí tí àkíyèsí fihàn wí pé Biritiko 🇬🇧 lo kalẹ sì ń gbà Toyin níyànjú wí pé, kò fi ọpọlọ ṣe òun to bá ń ṣe o. Bákan náà lo gba àdúrà wí pé, eléyìí yóò bá kalẹ àti wí pé, kò ní rí ibanuje mọ. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ náà lọ ń ṣe àdúrà fún onisẹ tíátà náà to jẹ ọmọ bibi ilú Edo.

Tí ẹ̀mí bá sì wà, ìrètí ò pín. Ire o! 🙏

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment