Smiley face

Dangote tí bẹ̀rẹ̀ si ni ṣe moto Peugeot jáde báyìí

Alhaji Aliko Dangote, ènìyàn dúdú to lowo ju lagbaye tí ṣetan báyìí láti má ṣe àwọn ọkọ pijó jáde ní ìlú Kaduna. Dangote Peugeot Automobile Assembly plant lagbo wí pé pupọ àwọn èròjà tí wọn yóò má lo ní wón yóò má ko wọlé láti òkè òkun. 

Gẹ́gẹ́ bí èrò àwọn ènìyàn tí a rí gbamu, bí ó tilè je wí pé inú awon  ènìyàn dùn fún itesiwaju yìí ṣùgbọ́n pupọ wọn ní kó fara mọ orísìí ọkọ, Peugeot, tí wọn fẹ má gbé jáde. Èrò àwọn ènìyàn ní wí pé àkókò ọkọ Peugeot tí kọjá lọ. 

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment