Smiley face

Ọkùnrin ní má fi oyún inú mi bí - @LindaIkeji

"Mi ò lè pa ayọ̀ yìí mora mọ. Ìdùnnú mi lo jẹ láti kéde rẹ fún yín wí pé, àkọ́bí ọmọ mi kò ní pẹ́ de ba mi lálejò ni nǹkan bí oṣù kan sì àkókò yìí" - Linda Ikeji, gbajugbaja akoroyin ayélujára kò lè pa ìdùnnú rẹ mọ́ra pelu bo se finu soyun. Kódà, ó sọ wí pé ọmọkùnrin ni ọmọ ẹ̀jẹ̀ ọ̀run tí nbo wá sílè ayé.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment