Smiley face

Ìwé ìròyìn Financial Times tilu London tàbùkù Buhari

Ìwé ìròyìn Financial Times tilu London tí toju onika mẹsan an kaa pelu bi won se gbe e jade nínú ìwé ìròyìn wọn wí pé, Aare Muhammadu Buhari kò ní òye ibi a gba ti a ba n sọ nípa eto oro aje. 

Ìròyìn tó jáde yìí ni ìwé ÌRÒYÌN Punch tilè Naijiria tún tẹ́wọ́ gbà ti wọn sọ dorin pẹ̀lú àlàyé to n so wi pe ọdún merin àkọ́kọ́ Buhari kò lojutu rárá nípa ètò ọ̀rọ̀ aje. 

Won rọ Buhari láti wo awokese àwọn ìlú bí Rwanda àti Ethiopia tó dabi eni wi pe awon ti gbeyanju púpò nípa àwọn ìlànà wọn nípa eto oro aje. 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment