Smiley face

Fonoloji: Aranmo (Assimilation) ninu ede Yoruba

Fonoloji: Aranmo (Assimilation) ninu ede Yoruba
Ninu folọnoji ede Yoruba, ohun ti a n pe ni Aranmọ (Assimilation) maa n waye nigba ti awon iro ohun meji ba di toko-taye. Eyi tunmu is ìlèpọ̀ laaarin awon ohun meji. 

Gege bi Kola Owolabi 1989 se saleye fun wa, iro kan le mu lara abuda iro keji nigba ti won ba di okan tabi beekọ.

Gege bi alaye Francis Oyebade, 1998, Oun se ninu alaye ti ẹ wi pe Aranmo yii le jẹ Anticipatory, eleyii ti yoo mu iro ohun isaaju lati yọ mọ iro eleekeji. Bakan naa ni iro tẹyin le yọ mọ ti isaaju eleyii to pe ni Perseverative Assimilation.

Ju gbogbo rẹ lọ, o dabi eni wi pe oko kan naa ni Francis Oyebade ati Kola Owolabi jo n ro.

Ninu Apeere Kola Owolabi

Ilé ìwé   = iléèwé
Ọ̀wọ́ ọ̀wọ́  = ọ̀wọ̀ọ̀wọ̀


Apeere Francis Oyebade

Ara oko = Araoko  
Ọmọ Ẹran = Ọmọeran


Gege bi a ti se alaye siwaju, èrò Kola Owolabi ati Francis kò yato si ara won. Kola Owolabi gba wi pe, ọ̀nà mẹta ni a le pin awon aranmo si ni ile Yoruba.

Awon ona meta naa ni

Aranmọwaju ati Aranmẹyin
Aranmọ alaiforo (alai-fo-iro) ati aranmo aforo (a fo- iro)
Aranmọ kíkún ati aranmo ẹlẹ́bẹ

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment