Smiley face
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts

Wọn tí dá eérú sójú sójà mokanla - Akoni ni gbogbo wọn

Tí ẹ bá wà nílè tẹ ẹ ń jẹyan oko, tàbí ẹ wá lóde àríyá níbi ti fàájì tí gbé dùn yungbayungba; ẹ má gbegbe wí pé àwọn kan wà l'Òkè Oya tí...
Read More

Ìbàdàn setan láti gbalejo Omoyele Sowore, oludije fún ipò aare lodun 2019

Gbogbo Ìbàdàn tí ń rọ kẹ̀tíkẹ̀ti báyìí láti gbalejo Omoyele Sowore, olootu àgbà àti oludasile ilé ìṣe ìròyìn Sahara Reporters, ẹni tí ń múra...
Read More

"Boko Haram pa ènìyàn méjìlá, wọn tún padà wá pa mẹẹdogun níbi wọn ti ń sìnkú àwọn méjìlá akoko"- BBC Hausa

Ileese ìròyìn BBC, ẹ ka tí èdè Hausa tí kéde bí àwọn Boko Haram ṣe pa ènìyàn méjìlá ni Zamfara. Bákan náà ni wọn tún padà wá lọ́jọ́ kejì níb...
Read More