Smiley face
Lẹ́yìn Ọlọ́run ìyàwó mi lo kan - Yemi Solade

Lẹ́yìn Ọlọ́run ìyàwó mi lo kan - Yemi Solade

Yemi Solade lọ ṣe àfihàn ìyàwó rè pelu akole tó sọ wí pé, lẹ́yìn Ọlọ́run ìyàwó òun ni ènìyàn tó kàn ninu igbe ayé òun.
Read More
Àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege to kò àwọn ọmọ ìta wọlé igbimo asofin

Àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege to kò àwọn ọmọ ìta wọlé igbimo asofin

Laarọ yìí ni àwọn ọmọ ìta yawọ ilé igbimo asofin àgbà Abuja tí wọn sì jí ọ̀pá àṣẹ sálọ. Ní báyìí àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege ...
Read More