Mo ti bere si ni se igbelaruge awon eniyan ti won sise opolo to gbamuse tabi awon eniyan ti Olorun fun lebun to joju fun idagbasoke awujo wa. Mo ti so nipa olotito eniyan kan ti won pe ni Sheu Aseyori. Nibayii, Ebony Finex Stitches tun ni awon eniyan tun so fun mi nipa re. Mo ti lo ba omobirin onise aso oge yii lati mo nipa ise re sii.
O so fun mi nipa iriri ati imo re nipa ise aso oge sise, bakan naa ko sai menu ba ohun to gbe de ilu Ghana ati Abijan eleyii to dale ojulowo imo aso oge ko to di wi pe o pada silu Nigeria. Ohun to jomiloju ti mo ba pade ni wi pe, pupo awon osere onitiata lo je wi pe odo omobirin yii ni won ti n ranso. Maa ma so fun yin siwaju si nipa awon alaye ti mo mu bo lodo Ebony Finex Stitches. Sugbo ko to digba naa, e le kan si won fun awon alaye nipa ise oge to gbamuse:"Olayemi Oniroyin, Ologini n peran ko meran dele ni ko je ki won fura pe ode gidi ni. Pupo awon ise mi ni awon eniyan ti ri lode ariya tabi lori telifisan, sugbon oruko mi o si lara re ni ko je ki awon eniyan mo. Sugbon lai pe, awa naa ko ni pe maa se igbelaruge ati afihan awon ise wa ki awon eniyan le mo wa. Sugbon awon Yoruba ni okookan bayii la n yose leku."
08063153975, 09081214120 BB pin: 56473367
0 comments:
Post a Comment