Muhammed Lawal Ogbeni Muhammed Lawal ni enikan ti da epo eebo lu lara ti won si sana si i. Lojiji ni gbogbo ara okunrin naa gbana, ti...
Read More
Home / Yoruba
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Showing posts with label Yoruba. Show all posts
Agbara Olorun fara han laaarin omi okun
Alagbara ni Olorun oga ogo. Ogangan ibi ni odo Mississippi ati Gulf of Mexico ti pade. Omi odo kan pon, ekeji si funfun. Bakan naa ni a...
Read More
Olubadan gba iyawo Buhari lalejo
Olubadan tile Ibadan, Oba Saliu Olasupo Adetunji Aje Ogungunnuso 1 gba Aisha Buhari lalejo ninu aafin re lojo ketadinlogun osu kerin odun...
Read More
Ara oto lati owo Tunde Kelani
Agbaoje ninu ise fiimu, Tunde Kelani, ti setan lati bo soju ise nipa fifi ojulowo imo ye awon eniyan ti won gbero lati di eni atata tay...
Read More
Mewaa sele lagbo amuludun
*Lanloodu ti le Wizkid kuro nile re ni Lekki *Surutu be sile laaarin She Baby ati Kemi Afolabi *Aye se iranti Hubert Ogunde *Toyin Aimak...
Read More
IROYIN OWURO ose yii kun fofo bi ataare
OGUN 2019: Tinubu, Yayi setan ati ba Amosun fa surutu * Aarin Asiwaju ati Amosun ko dan moran mo * Gbenga Daniel fe faramo Tinubu
Read More
Switzerland da N142b pada ninu owo t’Abacha jiko pamo
Sani Abacha Ijoba ile Switzerland ti kede wi pe, ogorun meje ati metalelogun milionu owo dola ilu Amerika ($723m eleyii to n lo ...
Read More
Nipinle Ondo, komisanna olopaa tuntun seleri lati segun awon Fulani darandaran
Gomina Mimiko ati Hilda Arabirin Ibifuro-Harrison Hilda to je komisanna tuntun fun ipinle Ondo ti salaye ninu oro apileso re ...
Read More
Buhari ti seto eyawo bilionu mewaa (N10b) fun awon odo ti ko nise
*Iwe eri agunbaniro NYSC ni won yoo fi ma ya owo naa Aare Muhammadu Buhari Aare Muhammadu Buhari ti se ifilole bilionu mewaa...
Read More
“Inu mi dun wi pe mi o jawe olubori gege bi gomina” – Alao Akala
Alao Akala Gomina ipinle Oyo nigba kan ri, eni to tun dije fun ipo gomina ninu eto idibo odun 2015, Oloye Adebayo Alao-Akala fi idu...
Read More
“Oseese ki owongogo epo robi o tesiwaju”- NUPENG
Egbe awon osise ti elepo robi ati afefe gaasi nile yii ti a mo si NUPENG, ( Nigeria Union of Petroleum and Natural Gas Worker s)...
Read More
Idanwo Jambu: 250 maaki ko to yan fanda fun olusedanwo mo
Awon omo onidanwo Jambu gba gbogbo oju titi kankan-ankan lose to koja ni agbegbe Maryland to kale siluu Eko Gomina Akinwunmi Ambod...
Read More
NIS ti n dogbon lati gba eedegbeta (500) eniyan senu ise nibonkele
Leyin asemase to waye lati eka ile ise ijoba ti n risi wole-wode ti a mo si Nigeria Immigration Service (NIS) to waye lodun 2014. N...
Read More
Niluu Ile-Ife, Ooni yan Obalufe tuntun gege bi igbakeji re
Ogbeni Idowu Olaniyi Adediwura Arole Oodua, Ooni Ile-Ife, Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi (Ojaja II) ti yan Ogbeni Idowu Olaniyi Adediwu...
Read More
Jegudujera: Ile ejo siwe esun Saraki lakotun
Awon Yooba bo, won tina ko ba tan laso, eje ki i tan leekanna. Ibi aroko ti si, ibe naa la a fabo si. Eleyii gele ni se apejuwe aare...
Read More
Iji nla ja nile igbimo asofin ipinle Ondo
*Won yo adari ile igbimo asofin, won tun da a pada lojo keji. Awon omo ile igbimo asofin ipinle Ondo gbimopo yo adari ile, A...
Read More
Buhari toro aforijin lowo omo Naijiria latari ina elentiriki to daku
*”Falala ni awon eniyan yoo ma gbadun ina elentiriki lati ose yii lo” - Lai Muhammed Aare Muhammadu Buhari Latari ina monamona ele...
Read More
E wo ohun ti Rotimi Amaechi se niluu Abuja
Rotimi Amaechi, Minisita fun igbokegbodo oko, se iranwo fun awon osise ijoba to pade lona nipa fifi oko re gbe won de ibi ise won niluu ...
Read More
Won fi ibon ko ifun omo ileewe jade ni Mile 12
* Oba Akiolu fara mo aba Ambode lati gbe oja Mile 12 kuro Leyin rogbodiyan to be sile ni agbegbe Mile 12 to kale siluu Eko laaar...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)