Orisiirisii awuyewuye lo ti n jẹyọ lati igba ti iroyin ti jade nipa bi won se wi pe Seun Egbegbe ji foonu ninu oja to wa ni agbegbe Ikeja niluu Eko. Sebi won ni ohun to koju si enikan, eyin lo kọ si elomii. E gbo ohun ti obirin naa wi nipa isele naa ninu fidio isale yii
0 comments:
Post a Comment