Smiley face

Fidio bi awon olopaa se mu Seun Egbegbe ni yii laarin ọja

Seun Egbegbe
Seun Egbegbe lagbọ wi pe o wonu oja to wa nI'keja lọ lọjọ kejilelogun osu kokanla odun 2016 lati lo ji awon foonu ti apapo owo won lo si bi nnkan bi milionu meji o le die. Fidio bi awon olopaa se mu Seun Egbegbe lo ni yii leyin asemase naa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment