Johnson Adeniyi |
Awon Yoruba bọ, won ni idi isẹ ẹni lati mọni lọlẹ. Johnson Adeniyi to jẹ ọkọ aarọ Toyin Aimakhu ki igbeyawo won to tuka, ti salaye bi ọpọlọpọ isẹ fiimu se kun ọwọ rẹ ni asiko yii, eleyii ti ko jẹ ko ni akoko pupọ fun ara bi awon igba kan sẹyin.
Bakan naa lo tun so wi pe, aimoye isẹ oun ni yoo jade ni akoko ọdun ti n bọ lona fun igbadun awon ololufẹ rẹ.
0 comments:
Post a Comment