Smiley face

Mandela Ji Dide!

Nelson Mandela, omo odun meerinlelaadorin (94 years) ti gbogbo agbaye gba gege bi baba ile adulawo ti pada wale leyin ojo mesan to se ni ile iwosan.

Ninu ile re to wa ni Houghton ni Johannesburg ni omoomo re Ndileka ti n fi ope fun Oluwa fun alaafia ara ti o pade sara baba agba awon.

Bakan naa ni gbogbo idile Mandela dupe lowo aare Zuma ati gbogbo ile adulawo fun aduroti won fun okunrin akoni ile adulawo ti arun ona ofun ti n ba finra lati bi ojo melo kan seyin.

Adura wa ni wi pe, Olorun yoo tun bo maa se aleekun ajinde ara fun Baba Ile Adulawo ti wa. Amin

Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment