Nibayii, eka ile ise ijoba apapo to n mojuto irinna ofurufu, Nigerian Airspace Management Agency ti gbegi le papako ofurufu Maiduguri to wa ni Ipinle Borno lati dawo lilo-bibo oko ofurufu duro titi osu keta odun 2014.
Aba yii lo waye pelu ipo abo ilu naa to mehe nipa bi awon Omo Boko Haram se n fitinati awon omo Naijeria ni apa agbegbe naa.
Lara itu awon omo Boko Haram eleyii ti won ti derujeje si Ipinle Borno ni bi won se ba awon ohun elo Nigerian Airspace Management Agency je. Won jo baalu bi meta won si pa omo osise alabo meji lojo keji osu kejila odun 2013.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment