Igba ti ife ba n dun lore n dun. Lowelowe ni Ayo Balogun fi n soro lori ero twitter re lenu ojo meta yii. Eyi si je ki ominu maa ko gbogbo awon ololufe orin re nipa wi pe ko maa lo je wi pe Wizkid ti ko Tania Omotayo sile.
Sugbon enikeni ko ti i le so pato, ati wi pe oro ife sooro dasi. Sebi awon Yoruba loni bo ti wu ki sanmo funfun to, dudu die yoo si wa. Bo ba tile je wi pe gbolohun-aso le wa laaarin won(eleyii ti ko si aridaju), a ko tile gba wi pe ife ti tan.
Sugbon gege bi oro ti mo fi side alaye mi, Igba ife ba n dun lore dun, ti ife ba ti tan ko sore mo.

Oro Awon omo olorin, igbeyawo won kii tojo. bakan naa lomo sori lodo awon elere fiimu. igbeyawon bii foonu china ni. o le rewa loju, ko aa tan ina yinginyingin. sugbon kii tojo. a fi ki Oluwa saanu fun won. Olayemi, ku ise, mo maa gbadun awon iroyin re nigba gbogbo. Olorun Oba yoo maa fun o se. Ilu New York lawa wa ti a tii n ka Olayemi Oniroyin. Olayemi o lenu
ReplyDeleteE se gan-an. Bi gunyan-gunyan ba gunya ire ti ko ba ri eni je, iru iyan bee kii se iyan ire. Bi roka-roka ba roka bi ko ba reni baa jeka re, bi oka oun ko tile lemo, oka bee kii soka gidi. Eniyan laso mi, e ti poju!
ReplyDelete