Ibanuje nla ni ki omo fi baba sile saye lo, edun okan nla lo je fun baba la ti tufo omo re.
Ojogbon Oluwole Soyinka ti padanu omo re omobinrin, Iyetade Soyinka eni odun mejidinlaadota(48).
Aisan kerekere kan lo mu Iyetade lo ni ile iwosan Ijoba Apapo to wa ni ilu Ibadan (UCH) nibi to ti n gba itoju.
Ekunrere iroyin nbo lai pe. A ko ni fi ibanuje sodun o.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
Olodumare yoo tu Baba,iya ati gbogbo ebi ninu yoo si dariji oku orun
ReplyDeleteGabriel Tola Aruwajoye.
Amin. E ko ni fi iru e gba Oo. E se gan-an
ReplyDelete