Nigba teni to foju n fi ona han oloju meji.
Aimoye elese meji ti n seru aro ti o le dide.
Ati se orire eda laye, owo Edua oke lo wa.
Ogbon se pataki sugbon ko si ohun to da bi ki Oluwa fun ni se.
Baba mimo, adura ni mo gba fun awon ololufe mi ti won fe mi ni gbogbo ojo.
Fi owo fun won lopolopo.
Se ona won ni rere.
So ibanuje won di idunnu.
Gbewon ga ju ero won lo.
Adura mi re e, Olu Olorun Orun. Amin
Olayemi.
0 comments:
Post a Comment