Baalu Jabo Ni Ilu Jamani Olayemi Oniroyin 1/13/2014 09:34:00 am Edit Baalu jet kan ti jabo ni ilu Germany eleyii to mu emi eniyan merin ti won mbe ninu oko ofurufu naa lo. Baalu ti a gbo wi pe o n bo lati ilu UK yii lo gbana je nikete ti akope re jakun wa sile ni agbegbe Trier. Gege bi awon osise panapana ti won sare de ibi isele naa se so, won ni oseese ko je wi pe oko ofurufu naa sanri mo opo ina kan ni. Share on Facebook Share on Twitter Share on Google Plus About Olayemi Oniroyin RELATED POSTS Baalu Jabo Ni Ilu Jamani Reviewed by Olayemi Oniroyin on 1/13/2014 09:34:00 am Rating: 5
0 comments:
Post a Comment