Oko ti nomba re je 14 C-74 DT lo gbana je losan ana ni nnkan bi ago meta ni opopona PTI to wa ni agbegbe Emasodje.
Awon eniyan merin pere lori koyo ninu ijamba ina naa pelu deraba to wa oko naa.
Gege bi awon ti ori ko yo se so, won ni obirin elesu kan lo wo inu oko naa pelu galoonu epo pentiro lowo, eleyii to joko siwaju. Won ni bi o tile je wi pe awon ero oko kilo fun dereba wi pe ko maa gbe Iya elepo pentiro, sibesibe Jagunlabi kotiikun.
Ojiji ni ina seyo eleyii to fi emi sofo.
0 comments:
Post a Comment