Smiley face

Irawo Osere Ti N Se AsoJu Glo Ti Bo Si Owo Aitel


Mike ati Segun Ogunsanya (Oga Agba ile ise Airtel)

Osere sinima, Mike Ezuruonye eleyii ti ile ise ibanisoro Glo ja ju sile gege bi asoju won ti a mo si anbasado ni ile ise Airtel ti ko owo tabua le lori bayii lati maa soju ile ise naa fun ipolongo ati ipolowo oja to kun fofo bi ataare.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment