Smiley face

Abami Omo To Ni Iru Nidi Ti Di Oosa Ajibo Ni Ilu India

Amar Singh to je omo odun mefa to wa ni ila oorun ilu India lo bere si ni wu iru nidi eleyii ti opolopo gba wi pe orisa obo to je okan lara awon orisa ti awon eniyan agbegbe ilu naa n sin lo pada wa saye gege bi eniyan.
 
Aye oloba ni omo yii je, abo goolu ni fi n jeun nitori awon eniyan gba wi pe orisa ni kii se eniyan lasan.
 
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment