Yinka Ayefele (MON) lo ti bere si ni kede fun gbogbo aye wi pe awon onijibiti, ole, 419, ika, abatenije, odaju, gbewiri, oloso-olosa kan ti lo si FACEBOOK ayederu kan lati maa fi lu awon eniyan ni jibiti ni oruko Ayefele.
Yinka Ayefele n ro awon ololufe re lati sora, ki won si yago ati ba eni naa sore.
Linki akantin fesibuuku ole naa ni yii nisale.
E yewo, to ba je ore yin e tete yo danu nitori kii se Ayefele gidi.

0 comments:
Post a Comment