Gomina tuntun ti gbogbo ara ilu dibo yan ni Ipine Ekiti, Ayodele Fayose ti tewo gba iwe eri iyansipo lati odo ajo ti n ri si eto idibo ti a mo si INEC.
Eto yii lo waye lana ode yii (26-06-14) nibi ti gomina ti n fi ileri re mule fun awon eniyan Ipinle Ekiti wi pe oun ko ni ja awon eniyan naa kule pelu bi won se fi owo sowopo yan oun soye.
Olusola Eleka to je igbakeji Fayose naa wa ni be. Ojogbon Layi Olurode to je alamojuto ati asoju INEC ni Guusu-Iwo Oorun Nigeria lo fi leta ayo naa le Ayodele lowo.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment