Smiley face

Bawo ni eniyan se n da iru ejo yii?

Omokunrin yii lo n gbiyanju lati na owo ji foonu lati oju ferase lai mo wi pe, onile ti reke re sile. Bo se nawo lati mu foonu ni onile fi ada ge lowo daale. Sapele ni isele naa ti waye.

Bawo ni eniyan se n da iru ejo yii?



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment