Smiley face

Fiimu Tuntun: Aye Etan (World of Deceit) lati owo Bose Oladimeji

Aye Etan
"Eniyan wọn, ara aye eniyan sòro..." Olayemi orin emi naa kọ, orin Araba Ifayemi Elebuibon ni. Awon Yoruba si bọ, won ni, aimoye iriri loju àgbà ti ri ki oju rẹ to ko wọnu. Bose Oladimeji, obirin bi okunrin ninu isẹ akin to lapọnja, ọdọmọde a fi gègé gbe itan kalẹ bi ẹni kọ epistu ọrọ Oluwa. 

Iba ọmọ Oladimeji!

AYE ETAN, sinima tuntun ti n so nipa iwa ọwọ ẹda eleyii to si n konilọgbon lati mọ nipa iwa ọmọ Adamọ ti n milu jinjin bayii. 

Atigba ti Adebayo Tijani ti gba irawọ meje nise to ba dari ti di ifọnkabalẹ fun gbogbo aye.

Muyiwa Ademola ati Bimbo Oshin kopa ninu eleyii bẹẹ lakitiyan won pegede. Eni wo fiimu naa lo le salaye.
Bose Oladimeji
Lara awon osere to wa ninu ere naa ni Afeez Eniola, Bose Oladimeji, Kemi Afolabi, Sheyi Ashekun, Bidemi Mustapha, Aishat Abimbola ati awon irawo osere mii. E ma gbagbe wi pe, Sunlight Distributions Ltd lo n pin lo si n ta fun gbogb aye.

Aye Etan, sinima tẹ ẹ gbọdọ ma wo ni! 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment