Smiley face

Fidio orin Bazooka ti jade lati owo Inspirashn, Grandpa Awon Girls

Bi o ba logbon orin gidi fi pamo lojo ti Inspirashn ba n korin. Orin ju orin lo, a jurawa lo ijakadi ko. O wu Edumare lo se ori ewa fakuko, o wu Oba oke lo gbe Inspirashn soke nibi ka korin to gbamuse. 

Tuntun leleyii, ti won pe akole re ni Bazooka lati owo Inspirashn ti won tun pe ni Grandpa Awon Girls. 

Nuel Views lo dari fidio orin naa nigba ti Lathamix je olootu amoju-ero to se orin naa jina to fi se gbo seti. 

Iroyin ko to afoju ba, e wo orin naa NIBI
Inspirashn: Bazooka 

Alaye ti agbenuso Inspirashn fi ranse si mi ni yii nisale:

"Inspirashn [@inspirashn] a.k.a Grandpa Awon Girls is here again with the visual to another smash hit titled Bazooka. This beautiful and colourful video was directed by fast rising creative director Nuel Views [@Nuelviews] and the song was produced by Lathamix."

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment