Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbe aye Olabisi K (38)

#ayeOlabisiK38


Sii Olootu,

Ibi ti mo so itan mi de ni ibi ti awon ẹni ibi yii ti n gbe mi lọ laaarin ọganjo oru.

Igba ti won de ori afara kan ti omi san ni abẹ rẹ ni won to duro.

Bi won se ni ki awon ju mi sinu omi ni mo taji loju orun.

Igba yii lo to ye mi wi pe oju ala ni mo wa ki i soju aye. Pelu ibeeru ni mo fi taji loju orun. Se ki n se wi pe ẹmi lo n ba mi soro?

Abi ko je wi pe awon kan ti n lepa emi mi. Olorun Oba alaabo, maa fi abo re bo mi. O digba

Emi ni tiyin ni tooto,

O si n tẹsiwaju...
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment