Smiley face

E ku odun tuntun 2017: Odun ayo ni yoo je fun wa

E ku odun tuntun! 

Ti ko ba seti lagbari bi apola igi lori eniyan ko ba ri. Ope lowo oluwa oba, ti keinkein ko ba tobi bi esin atapa ni ko ba tani. Ope pataki lowo awon eniyan ti won on se atileyin fun mi lojo gbogbo. 

Opo won lo ya mi logbon, awon kan fun mi ni iwuri, awon kan si gbe mi laruge. 

Odun 2017 yoo san wa sowo, yoo san wa somo, aiku baale oro. 

Mo dupe lowo yin pata. 

Happy New Year!!!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment