Smiley face

Idi ti Toyin Aimakhu fi pa oruko re da si Toyin Abraham ni yii

Toyin Abraham

Awon Yoruba bo, won ni to ba se wuni laa se imole eni, eniyan le fi itan elede je saari to ba ti fe bee. Ati wi pe, bayii ni i se nnkan mi ko yipada.

Sebi won kini yii nnkan mi ni o yato si kini yii nnkan wa. Agba oserebirin onise tiata, eni ti gbogbo eniyan mo si Toyin Aimakhu tele ti pa oruko re da si Toyin Abraham bayii. Gege bi atejade ti omo bibi ilu Edo naa fi sita, o ni aba tuntun lati paaro oruko naa da je ajoro gbogbo ebi.

Pupo ninu awon ololufe re lori ayelujara ni won tewo gba oruko tuntun naa pelu idunnu. Sebi won ni eni aye n fe ko larun kan lara. Awon eniyan die lasan ni won ko kaakun nigba ti awon kan fi n se awada.

E je ka wo die ninu ero awon eniyan nipa iyipada oruko naa.


 z_i_o_n_i_t_: @toyin_abraham You are a seed of Abraham & Abrahamic covenant is at work in you#Your former toil shall be forgotten and there will be joy and gladness and laughter in the forthcoming year🙏🏻Seek God & set your focus on Him & shun all manner of distractions#iKnow The Lord wants to USE you to bring MANY to Him#You were born a star.Keep beaming Toyin💕🙏🏻


dutandiva:Name changed or not,u are and will always be the best @toyin_abraham your personality intoxicates me😇😅😅 #Worldbest I love u so very much😍😍welcome back!


serifatu:Toyin Abraham is a great name. God promised Abraham. He said Abraham l will make you a great nation. Toyin Abraham God will in His mercy make you a great nation. He said Abraham l will bless you and make your name great, l will bless those who bless you and curse those who curses you. In you all the families of the earth shall be blessed. Toyin Abraham God will in his mercy bless you and make your name great. He will bless those who bless you and curse those who curses you, in you all the families of the earth shall be blessed in the mighty name of Jesus Christ.Amen. You are highly blessed darling. Love you always.


toyintitilayomi:I just hope this is for real n not d other way round.Either way u r much loved always @toyin_abraham


Ninu itopinpin Olayemi Oniroyin Agbaye, lara alaye ti a gbo lawon ibi kan ni wi pe, ipaorukoda Toyin ko se leyin bi Seun Egbegbe se yi oruko re, Toyin Aimakhu, monu erofo ati idoti lodun 2016.

Won ni pupo awon iroyin to jade nipa bi Seun Egbegbe se lo ji foonu loja Computer Village to wa ni agbegbe Ikeja niluu Eko lo gbe oruko Toyin Aimakhu sori. 

Oye won si ni wi pe, bi won se n pe Toyin Aimakhu mo Seun Egbegbe ni iroyin naa n se akoba nla fun Toyin gege bi ilumooka amuludun ile adulawo.

Fun iranti, Seun Egbegbe ni ololufe eleekeji ti won ri pelu Toyin leyin ti yigi re pelu Johnson Adeniyi tuka losu kejo odun 2015.

Toyin ti bere igbe aye tuntun lodun 2017 pelu oruko tuntun, awon idoti, egbin, ati akoba 2016 si ti payinda leyin re bi igba ti keregbe to fo pada leyin odo.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment