Smiley face

Awon oyinba pon Oonirinsa le niluu London: Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi gbayi niluu Oba

Ka ma paro, awon oyinbo se aponle Oba Adeyeye Enitan Ogunwusi niluu London. Won se alaye Arole Oodua gege bi ologbon eda ati asaaju to se tele. Oko Wura ola naa ko si gbeyin nipa sise afihan asa Yoruba gege bi ohun kan to rewa to si gbayi pupo.










Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment