Smiley face

Orekelewa obabirin MOREMI gbe asa Yoruba soke niluu London

 Sebi e mo wi pe Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi si wa niluu London, lara awon to koworin pelu Ojaja II ni Obabirin Moremi asiko yii eleyii ti oun naa n se afihan asa Yoruba ni gbogbo ibi ti won de niluu Oba Elisabeeti.




Moremi gbade Ojogbon Jega niluu Londo

Orisun foto: Ayo George
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment