Smiley face

E kaabo sinu osu ayo tuntun

Ninu osu tuntun, e le se ipinnu tuntun ki e si muse. Ojuse yin ni lati se akitiyan imuwasaye ero rere ti e ni lokan nipa igbe aye yin.

Ti e ba n gbo 'gbe-e-gbe-e-gbe', ti e ko ba dide lati gbe e, eyinkule yin ni won ma gbe si.

Ko si oro lenu alaseti, alaseyori laye n ponle. E ma je ko reyin, orun to wa loke to lati gbe aso. E ma joko lasan, e ri daju wi pe n gbiyanju nigba gbogbo.
Adura mi ni wi pe, Edumare yoo fi ibukun si gbogbo igbiyanju yin pata.

E ku amojuba osu tuntun, osu ayo!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment