Smiley face

"Afaimo ki tomato ma gbowo lori pelu kokoro Tuta Absoluta to wole de"- Awon onwoye lo so bee

Kokoro ajenirun kan ti n je Tuta Absoluta ti yawo awon ijoba ibile bi meta ni Ipinle Gombe ti won si ti je gbogbo oko tomato won tan pata.

Awon onwoye si ti bere si ni kesi ijoba lati wa wokoko fi sade lati ma je ki owongogo tomato mi tun waye nile Naijiria.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment