Smiley face

Afolasade Alli: Orekelewa omo olojo ibi

Gbogbo eni logbon lori ko loniwa tutu. Gbogbo oniwa tutu ko leni ire. Afolasade Temitope niwa tutu, o logbon lori bee ni inu ire re po lapoju.

Ogbontarigi sorosoro ti won fori bale fun lojokojo.
Orekelewa ti n dan gbinrin bi egbin.
Olori Jesu omo Alli ti jelo kafara o to ja.
Ota n se lasan ni, irawo re ni i tan loke.

Igba odun, odun kan ni lase Edumare.

#HAPPYBIRTHDAY

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment